The cognomen of Olomu goes thus;
Omo olomu aperan
Omo oloro agogo
Omo asingba l'ona t'omu
Omo b'ewure ba sonu l'omu
E ma mo mu lo mi
Tani n ba baba won s'egbe gberangberan
Bi aguntan ba sonu l'omu
E ma mo mu lo mi
Tani n ba baba won s'egbe gberangberan
Adie opopo ti o ba sonu lomu Aperan
N'ile omo Awobimpe
E ma mo mu lo wa
Awa k'iba baba won s'egbe gbeyegbeye
Amo bi wondia rogbodo ba sonu l'omu
E ma ran elese wa p'emi
Elesin ni ki e ran wa si mi
Nitori pe awa ni omo a r'opon nla j'omitoro esin
Samu samu ki i koro l'omu
Ewu iyan d'Omu o d'otun
Asese gun iyan d'Omu o d'otubante
Omo olomu aperan
Omo oloro agogo
Omo asingba l'ona t'omu
Omo b'ewure ba sonu l'omu
E ma mo mu lo mi
Tani n ba baba won s'egbe gberangberan
Bi aguntan ba sonu l'omu
E ma mo mu lo mi
Tani n ba baba won s'egbe gberangberan
Adie opopo ti o ba sonu lomu Aperan
N'ile omo Awobimpe
E ma mo mu lo wa
Awa k'iba baba won s'egbe gbeyegbeye
Amo bi wondia rogbodo ba sonu l'omu
E ma ran elese wa p'emi
Elesin ni ki e ran wa si mi
Nitori pe awa ni omo a r'opon nla j'omitoro esin
Samu samu ki i koro l'omu
Ewu iyan d'Omu o d'otun
Asese gun iyan d'Omu o d'otubante
0 comments:
Post a Comment